AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language

Ẹ kọ Software Testing Ati Automation, Test Analyst, QA Tester, Software Test Engineer ati bẹ bẹ lọ ni ede Yoruba

Ratings 4.54 / 5.00
AToZ: Software Testing and Automation In Yoruba Language

What You Will Learn!

  • Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation
  • A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications
  • A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database
  • A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications
  • A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver
  • A o kọ lati lo Exploratory Testing
  • A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database
  • A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard
  • A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database
  • A o kọ Data Migration Testing
  • A o kọ lati le Report Bugs Tabi Defects
  • A o kọ End To End Testing
  • A o kọ Regression Testing
  • A o kọ lati lo MSSQL Server Database fun Extract Transform Load (ETL Testing) ati Database Testing
  • A o kọ lati le Create Test Script Template pẹlu Microsoft Excel fun Desktop, Mobile ati Web Applications
  • A o kọ lati Gain Working Experience As a Primary Tester at bẹ bẹ lọ

Description

Ẹ kabọ si course ton jẹ Kọ Software Testing Ati Automation Pẹlu (Real-Life Projects).

Lakọkọ ẹ jẹ ki a ni lo kan wipe course yi ma jẹ hands-on training tutorial (itumo nin pe 90% practical ati 10% theories). Kiko ni mi mo.

Ninu Course yi ẹ ma learn step by step Manual and Automation Software Testing (Functional) ti a ma lo WinAutomation, Selenium WebDriver 3 ati iMacros browser addons fun automating the Functional part of Web Applications pẹlu over 20+ real life projects.

Software Testing Manual ati Automation jẹ most important skills lati le test front-end ati backend Web Application, Desktop Applications ati Mobile Apps. Paapa ju li lo iMacros ati Selenium WebDriver 3 fun GUI automation, Software Testing Automation je popular larin large community.

Course yi structured si ọ nọ pupọọ:

Awọn ẹkọ yi pisi video screencast ati guide, Homework wa ni be ti a ma se, Ninu ẹkọ yi, a o kọ lati Setup Working Environment fun Software Testing ati Automation, A o kọ In and Out Functional Testing fun Web Application, Mobile Apps Ati Desktop Applications, A o kọ lati lo SQL Server Management Studio (SSMS) lati Query SQL Server Database, A o kọ lati lo Selenium WebDriver fun Automating Web Applications, A o kọ lati lo Java Eclipse Integration Development Environment (IDE) pẹlu Selenium WebDriver, A o kọ lati lo Extract Transform Load (ETL Testing), MS Excel, Notepad++, Test Script, ati Java Code Templates, A o kọ lati lo SQL Server Integration Services (SSIS) lati Upload Data sinu SQL Server Database, A o kọ nipa Basic Microsoft Excel (Spreadsheet) ati Microsoft Word (Document) Object fun Creating Simple Dashboard, A o kọ bi a o ṣe Migrate Microsoft Access Database lọ si MSSQL Server Database, A o kọ Data Migration Testing, A o kọ lati le Report Bugs tabi Defects ati bẹ bẹ lọ.

This course is backed by udemy's 30-day money back guarantee. If you are not satisfied for any reason, you will get the money back. In addition to that you will keep all the code files of the course as a thank you for trying out the course !!!

Who Should Attend!

  • Ẹkọ yi wa fu ẹni ti o ba fẹ di :-
  • Test Analyst
  • Software Quality Assurance Tester
  • Mobile Tester
  • Web Application Tester
  • Software Test Automation Engineer
  • Ati Ẹni ti o ba fẹ revise lo ri Testing Skills

TAKE THIS COURSE

Tags

  • Automation
  • Software Testing
  • Selenium WebDriver

Subscribers

84

Lectures

71

TAKE THIS COURSE



Related Courses